Showing: 1 - 1 of 1 RESULTS

Home About Contact Us. Breaking News. Asa Igbeyawo ni Ile Yoruba. Asa ati Owe 0. O je ohun Pataki fun okunrin tabi obinrin lati se igbeyawo ni igba atijo. Ni igba ti a ba gbadura fun eniyan ni ile Yoruba pe yoo se anfaani, ibi ti anfaani yoo ti bere ni ibi igbeyawo.

Bi eniyan kan ba wa ti ko ba fe aya nigba ti gbogbo awon egbe re nfe aya, oju ko ni kuro lara re, enu ko si ni kuro lara re pelu; gbogbo or ti awon eniyan ba sin so sii ni yoo ma toka sii pe ko ye ki eniyan ya apon apon ni okunrin to ti to ni aya, sugbon to ko lati ni aya.

Gege bi owe awon Baba wa to so wipe bi ko ba nidi obinrin ki je Kumolu; bi ko ba ni idi, eniyan ki ded ya apon. Idi re niyi ti o fi je wipe gbogbo awon ti o ba ti ya apon ni nwon ma n fi ilu sile ni atijo, paapaa tie nu ba poju lara won. Gbogbo iriri ti a n ri lode oni ti fiha w ape eniyan le ya apon ti o ba wuu, nitori bi o ba se wu eni ni a se nse imale eni. Nigba ti odomokunrin kan ba ti balaga, awon obi re yoo ti bere si fi oju sile boya nwon a le ri omobinrin kan tin won yoo fe fun omo won.

Omokunrin yi paapaa laije pe enikeni so fun un, yoo bere si se finnifinni ju ti ateyinwa lo; yoo we nigba meta loojo, yoo toju eyin, enu, eekanna owo ati tese, gbogbo ara yoo si maa jolo. Ni kete ti okunrin ba fi oju kan wundia omobinrin ti ko ti mokunrin ti o je oju ni gbese, ise wa di ti alarina.

Alarina ni eni ti o ngbokegbodo laarin omokunrin ati omobinrin ti wo ba ni ife si ara won. Awon obinrin lo saba maa nsise yi daradara. Ise alarina ni lati wa idi ohun gbogbo kinnikinni nipa omobinrin yi.

Idi re ti a fi nwa idi ni wipe ko si eni ti yoo fe gbe eni ti won n dete ni idile won, tabi iran asinwin, tabi obinrin onijagidijagan ni iyawo. Ise alarina ni lati pon ati lat ge omokunrin yi loju omobinrin ki o si la oju agi si agi yoo seto bi omokunrin yoo se pade omobinrin. Leyin igba ti alarina ba ti la oju awon mejeeji kan ara won, omokunrin ati omobinrin yi yoo bere si pade ni orisirisi ibi labe igi odan nigba osupa, ni eyin ilea won omobinrin.

Leyi igba ti won ba ti se eleyi fun igba pipe, omobinrin yoo wa je hoo fun lati gba beni yoo so fun omokunrin ki o seto bi baba ati iya oun yoo se gbo nipa ore won. Gbigba ti omobinri gba yi ni awa Yoruba npe ni Ijohen tabi Isihun. Leyin igba ti omobinrin ba ti juwo sile patapata, omokunrin yoo lo so fun baba re pe oun ti ri ododo kan ti o pupa, ti o si lewa ni ile Lagbaja tabi Lakasogbe ti oun fe ja.

Baba re yoo wa bi lere boya ododo naa yoo see ja tabi ko ni see ja. Omokunrin naa yoo wa so gbogbo adehun ti oun ati omobinri yi ti se fun ara won. Eyi ni yoo fun baba re ni anfani lati lo baa won agbaagba adugbo re soro gegebi won yo se lo toro omo.

Ni igba kini tin won yoo lo ri baba omobinrin, baba omokunrin ati omo ile kan tabi meji ni yoo lo. Owuro kutu hai ni nwon si maa nrin iru irin yi. Nwon o ko, nwon yoo sir o fun baba omobinrin. Oro yi ko ni je kayefi si baba omobinrin yi notori o ti bere si ri irin ese omo re. Idahun ti baba yi yoo si fun awon wonyi nip e kii se oun nikan lo bimo yi ati pe kin won wa pade molebi oun ni ojo bayibayi.

Leyin igba ti won ba ti toro omo tan, idana ni gbogbo won yoo fi okan si. Gbogbo awon ti o ye kin won gbo nipa itoro ti nwon ko gbo, ati gbogbo awon ti o gbo ti won ko ri aye lo, akoko niyi lati fi owo si.

Awon idile mejeeji yoo ranse si awon eniyan won nibikibi ti nwon ba wa. Idana yi se Pataki pupo nitori ibe ni awon idile mejeeji ti maa npade lekunrere. Ni ojo idana yi awon iyawo baba omobinrin ati iyawo baba omokunrin yoo pagbo ere, olukuluku won yoo maa ki oko won.

Owuro kutukutu tabi irole patapata ni a nse idana. Lati ile omokunrin ni nwon ti maa ru gbogbo ohun idana wa.Yoruba bo won ni Agbalagba to ba faaro sere yoo fojo ale gbaaru ati pe apalara, igunpa ni iyekan eniyan. Idi ise eni ni a ti n moni lole. Asekere ko se nibi ana, koko pataki ti awon ipede wonyin n fi idi i re mule ni pe. Idi ni lati mo ise ti Eledaa yan mo omo lati ode orun.

Idi niyi ti yoruba fi maa n wure pe ki Olorun ma je ki a se ise onise o. Ise ni ogun ise tepa mo ise re ore mi. A ku imura odun keresimesi.

Odun a yaabo fun gbogbo wa o!!! Like Like. You are commenting using your WordPress. You are commenting using your Google account. You are commenting using your Twitter account. You are commenting using your Facebook account. Notify me of new comments via email.

Notify me of new posts via email. December 21, Like this: Like Loading Itan Efunsetan Aniwura. Amin, lase Edumare. Leave a Reply Cancel reply Enter your comment here Fill in your details below or click an icon to log in:. Email Address never made public. Post to Cancel. Post was not sent - check your email addresses! Sorry, your blog cannot share posts by email. By continuing to use this website, you agree to their use.

To find out more, including how to control cookies, see here: Cookie Policy.Yoruba is as sweet as honey This is the game:Complete a proverb Translate in english if you can,for non-Yoruba people ,then start another one to be completed by another user. You can start another one if you can't complete the previous one to be completed by soneone else. If your proverb can't be completed for a while,please help complete it. I don't want the thread to be completely in yoruba so others can learn.

You will be amazed how much you know and you don't know Eni mo eyi,komo iyen,lo di Ifa fun Orunmila to lo re ko Ifa lodo omo re Amosun He who knows this does not know that,this is why Orunmila learnt some Ifa verses from his son.

No proverb is too simple! Sorry for the long intro MisterDreamz : Oya oo Ere ti beere! E pari owe yi: Ile oba to jo RoaringLion11 Ile oba to jo ewa lo bu so The king's palace that got burnt,will be rebuilt to be more beautiful than the previous In situations of loss,I regard myself as a king with burnt palace and make better comebacks This proverb became one of my favorites after I first heard it from my grandma didn't understand it then.

Sorry for the digression! MisterDreamz : Ile la n wo,ki a to so omo ni oruko. All good though Cheers. All good though Cheers wow Ese pupo! All rights reserved. See How To Advertise.Obatala je iranse eledumare,eni ti o gbe ere awon eniyan ti olorun si fi emi re si inu wa,oba funfun igbakeji olodumare, eni ti olodumare fi se olori gbogbo eda ti o da si aye lati fi ona han awa omo adamo,gege bi awon oni imo won ni obatala je egbon fun oodua,olodumare fun obatala ni agbara lati pa ati lati ji eniyan.

Odofin ogbolu. Ojo kinni to nikoyi ku, oju mi paa lose agba ni mi Ko tii da,sugbon mo kuro lomo agbekorun lo inu oko. Won gbele won bo onikoyi mo nipekun orisanla,agbede gbede onikoyi lo sun ibe,Atari onikoyi Ko sun ibe, eyin lomo asiju apo piri dagba ofa sofun,pofun yoo yo dagba ofa sile,omo aku fepo tele koto,omo igunnugun bale won a jori akalamagbo bale won a jedo.

Gege bimo se n babo lapa kiniE dami lohun ibi aye nlo.

ere onise ni ile yoruba

Amon lasiko yii, Ibaje ti wa dewa sorun wa,Atomode, Atagbalagba, yala Obinrin ni tabi Okunrin jiji gbe ni. Agbe to ba soko nu, a ko sapo ebi. Ki a ronu si gbolohun yi, Ifa a gbe wa o. Awon to laye o ni je a sise. O dabo! Lati Owo Olalekan Oduntan. Ninu ookanlenigba awon irunmole bi Ogun, Oya, Orisa-oko, Aje ati bee bee lo, okan pataki ni ilu je. Agalu ni a mo oruko ilu si ni igbati o wa laye ki o to wa di eniti ori sa da loni.

Alagbara ati alakitiyan ni Agalu je. Eleyi si jeki opolopo eniyan ni ife re ti won si npe ni i amuludun. Nigbati Agalu jade laye,inu igbo ni won sin si. Igi ti o hu ni ibi orori re ni won npe ni Omo ti won fi ngbe ilu loni. Eleyi lo fa ti owe Yoruba kan fi so wipe, opo igi lo nbe nigbo ki a to fi igi Omo gbe gbedu.

Ati igbati Agalu ti jade laye ni o ti wa ni ipo Orisa ti won nbo kaakiri ile Yoruba loni. Bi a ba fe bo Agalu, a ni lati wa akuko adiye to ko jaye jorun, atare, oofunloju, obi abata oloju merin ati amaraya ti won npe ni sinaapu. Ilu sise je ise ajogunba tabi didanileko nipa re. Leyin eyi, ilu ti dele, o di sisa. Gudugudu ni baba ilu nitori ohun ni o di ilu mu. Gangan tabi Iya ilu ni asiwaju, kerikeri ati kannango lo tele.

Leyin eyi, ilu ti pe ki awon onilu ma fi dabira loku. Ilu ma nse bebe nibi igbeyawo, isile, nibiti won ti njoye, nibiti won ti njoba ati bee bee. Gbogbo ogbon ni awon Oyinbo ti da lati le jeki a ma a lu Iya ilu latori ero gegebi won sese fun agogo, sekere ati awon ilu toku, amo ko sese. Gbogbo awon odo ni won mo bi won ti nse ilu ti won si tun mo ilu lu pelu.

Gbogbo awa omo Agalu,ilu a maa gbe wa o. Ni igba iwaseewe ati egbo ni awon baba wa fi n se iwosan, a si ma a je bi idan fun won. Aisan orisirisi ni won a ma fi ewe ati egbo wo bi i arun Iba, roparose, ijuarun ibalopo, eje riruito sugaaato to san ati bee bee lo.E ku igbiyanju o!

A dupe;a du pepe okun fun ise nla ti e se yii. Olorun a sagbara dotun. Yoruba o gbodo ku o. You are commenting using your WordPress.

You are commenting using your Google account. You are commenting using your Twitter account. You are commenting using your Facebook account.

Notify me of new comments via email. Notify me of new posts via email. Eku itadi greetings for farting mess. Eku ireju greetin someonr relaxin. A jee yira o When sum1 is eating. Moki ota moki ope when people are playing game like draft, ludo, card, e. Eku ewa oo for sum one making hair. Eku abo some one come back.

Eku ile o Greetin when someone just arrived at home. Eku alejo when someone is having a visitor.

ere onise ni ile yoruba

Onya aya o for hairdresser. Eku ijoko o when people are sitted E ku ojo meta Quite an age Eku amojuba when any of ur relative just arrived from the journey. Eku iso when someone mess Eku iyaleta towards afternoon Eku ile de when any of ur relative is nt around Eku igbadun. When sumone is flexin Eku ojo meta long time no see E ku ise well done Ekun irole Gud evenin. Eku ara fe ra kun when some1 dead yesterday. Eku iyaleta o 10am to mid day greetings Oko aare fo oooo, greetings to driver Aroko bodun de o for famers Eku iduro when u stand eku erin when u laugh Eku owo lomi o the woman that just put to bed.

Eku osi when someone is doing rubbish E ku ay se greetings 4 doin nothing Eku ayeye oni greetn wen avin a party E ku orire o when some one purchasing car or recieving promotion letter E ku afere yii when the weather is cold Eku ise o greetings someone dat is working E ku orinrin when it newly rain and there is cold E ku ewu ijade Wen som1 is dedicatin a child EEKU ILE when someone arrived 4rom another place. Eku ijoko if a passer by wants to greet people sitting down.

Eku imu enu duro o when fasting.

ASA ati ISE abinibi

Eku ori ere ooooooooooo When celebrating a good thing. Share this: Twitter Facebook. Like this: Like Loading December 27, — pm. Bolaji June 13, — pm. Post author yoobaroots August 14, — pm. Alagbaademot July 20, — pm. Ayo November 16, — am.

Awon Orisa Nile Yoruba

Leave a Reply Cancel reply Enter your comment herePost a Comment. Powered by Blogger. Blogger templates. Free blogger templates. Posts RSS. Comments RSS. Home About Contact Subscribe. Toggle navigation. Awon Orisa Nile Yoruba. Bi a ba n soro nipa awon orisa nile Yoruba, tabi ka so wi pe ti a ba so nipa awon ibo awon babanla awon Yorubawon po sua bi omi ti ko see ka.

Amo a o lo anfaani yii lati fi menu ba die lara awon orisa:. Oun naa ni a tun pe ni Orunmila. O je orisa kan to Pataki ninu awon ibo nile Yoruba. Ifa tun je eleri ipin nitori pe awon Yoruba gbagbo pe Ifa lo wa lodo Eledumare nigba ti olukaluku n yan ipin re. Bi nnkan ba wa di wi pe o ruju ninu irinajo eda nile aye, Ifa ni awon Yoruba yoo to lo fun iwadii ati ibeere ti o ye.

Eyi toka si I wi pe eniyan gbogbo ni n beere lowo ifa, Ifa kii beere lowo eni kan. Ko si ohun yoowu ti a ba ba lo si odo re ti ko ni di ero. Okan ninu awon orisa Ibinu Eledumare ni Ogun. Gbogbo eni ti n ba n lo irin, ti Ogun ni won se. Orisa Ogun ni Ogun I se, ode harau si ni pelu.

A gbo wi pe oun lo fi ada owo re lana fun awon orisa yooku lati koja laarin igbo to di pingunpingun. Nigba ti a ba n bo Ogun, gbogbo ode ilu lo gbodo pese. Awon ijoye ilu ko ni gbeyin, bee ni gbogbo awon to n sise to jemo irin gege bi a ti toka si saaju. Awon ounje ti won maa n ko wa si idi Ogun niwonyi: Eyan agbado, eyan eree, emu ati aja ti won yoo be si idi Ogun.

Won tun ni lati ta mariwo si ibi ojubo Ogun. A ti ko nipa orisa ti a n pe ni Sango.

ere onise ni ile yoruba

E ni anfaani lati ka nipa awon ekunrere alaye ti a ti se nipa [ Orisa Sango ]. Okan ninu awon orisa ti ko see fowo ro seyin naa ni Osun.

Yoruba Songs LyricsPedia: Ultimate List of 200 Yoruba Gospel Songs Lyrics & Videos

Obinrin ni, iyawo Sango si ni pelu. Bo tile je ibo Osun maa n waye pelu ayeye ni odoodun, sibe bibo ojoojumo ko kere. Ilu Osogbo ti di ilu ti gbogbo eniyan ka si ibi to wa fun gbigbe Osun laruge.

Eleyii si ti je ki orisa Osun gbayi pupo. Sugbon kii se ilu Osogbo nikan ni won ti n bo Osun. Orisa yii wa laarin ibo jakejado ile Yoruba. Nibi ti odo Osun gan-an ko ba si, won a maa so oruko odo miiran ni odo Osun lati maa bo orisa yii nibe. Awon nnkan ti won fi n bo Osun ni wonyi: obi, akuko, igbin, agbo tabi ohunkohun ti awon ti Osun ti se loore lodun esin ba fi je eje.Yor jss1 6.

Se alaafia ni gbogbo ile wa o? Leta kiko pin si gbefe ati aigbefe a bee ni b bee ko d emi ko mo Ipin B 1. Ki ni oro-ise? Daruko ona merin 4 ti a pin oro-ise si 2. Se ekunrere akaye nipa oge sise 3. Jss2 6.

Posts navigation

Ta ni Yoruba gba ni Arinurode? Iru asa iran-ra-eni-lowo to jemo igbeyawo ni a owe b aaro d ebese Iru ohun wo ni a maa n fi sun iyere ifa?

Ko aroko onisorongbesi o keere tan eyo oro 2. Se ekunrere alaye nipa ere onise 3.

Orisun Yoruba - Latest Yoruba 2018 History By Amb. Olayinka J. Adesina

Ta ni Eledumare? So idi merin 4 ti awon Yoruba first feran Eledumare.

ere onise ni ile yoruba

Daruko awon ewi to jemo esin ibile. Post a Comment. Davis Cup B. Ogbe Land Court C. Lord Runners Competition Physical education aims at developing person on the following except A. Mbombo dance B. Epo dance C. Break dance We play computer game with the following except A. Search This Blog. Monday, 10 July No comments:. Newer Post Older Post Home. Subscribe to: Post Comments Atom. What is the probability that the selected ball is black A.

What is the difference in latitude A. What is the base radius of the cone A.